Efe Irele
Efeilomo Michelle Irele ni a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsàn án.[1] Ó jẹ́ òṣèré àti aláwọ̀ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Orúkọ tí gbogbo ènìyàn mọ ọ sí ni Efe Irele.[2]
Efe Irele | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Efeilomo Michelle Irele |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Website | efeirele.com |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayè rẹ àti iṣẹ́ rẹ
àtúnṣeEfe Irele bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aláwọ̀ṣe rẹ ní ọmọ ọdún márùndínlógún. Ó ti farahàn nínú oríṣiríṣi ìpolówó. Ó gba oyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Sociology láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Bowen àti oyè ẹlẹ́ẹ̀kejì nínú ìṣàkóso ènìyàn ( Human Resources Management) láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Chester ní Uk.[3]
Efe Irele dáwọ́lé iṣẹ́ àwòṣe fún àwọn òṣèré, ó sì tayọ nínú àwòrán fídíò ti Like to Party èyítí Burna Boy ṣe ní ọdún 2012. Ó tún tayọ nínú àwòrán fídíò ti Sade láti ọwọ́ ọ Adekunle Gold.[4] Efe ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àti eré ṣíṣẹ ti Nollywood. Lára àwọn sinimá yi ni Real Side, Chics, Wrobg Kind of war, Ire's Ire, Zahra ati Scandals.[5]
Philanthropy àti àwọn àmì ẹ̀yẹ.
àtúnṣeEfe ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀ Efe Irele Autism ní ọdún 2018 láti ṣe ìtọ́jú fún àwọn ọmọdé autistic.[6]
Year | Award | Category | Result |
---|---|---|---|
2018 | City People Entertainment Awards | Best Upcoming Actress of the Year (English) | Won[7] |
Year | Award | Category | Result |
2018 | City People Entertainment Awards | Best New Actress of the Year (English) | Won[7] |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Efe Irele Biography". MyBioHub. 2017-09-28. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ "She’s a Rising Star! See Efe Irele’s Promo Shots by Kelechi Amadi-Obi". BellaNaija. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ "'Winning 2 Major Awards In One Night Is a Big Deal For Me' - Fast Rising Actress Efe Irele Tells City People". City People Magazine. 2018-09-20. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ "I Am Not Going To Expose My Body For Attention -Efe Irele". Nigeria Films. 2017-03-04. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ "I’ve a jealous lover — Efe Irele, Actress". Vanguard News. 2018-10-20. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ "Citer". Citer. 2020-01-01. Retrieved 2020-10-06.
- ↑ 7.0 7.1 Àdàkọ:Cite News