Efunroye tinubu

Olóṣèlú

Abí arábìnrin "Efúnpòróyè Ọ̀suntínúbu Olúmọ̀sà" ní odún 1810. Arábìnrin yii jẹ gbajúgbajà onísòwò nípa òwò erú . O jẹ ẹni tí o gbajúmò ni ìlú Èkó nígbàtí Ọba Adéníji Àdèlé , Olúwolé, Akíntóyè àti Dòsúmú wa lórí oyè nìgbà náà. Abí akínkanjú obínrin yii ní agbẹ̀gbẹ̀ ojókòró ní ìlú Ẹ̀gbá ti orúko bàbá re a sì maa jẹ Olúmọ̀sà. A gbẹ́ arábìnrin Tinúbu ni ìyàwó ní òpò ìgbà. Ọko àkókó re wa láti ìlú Òwú tí o sì bi ọmọ méjì fún. Léyìn tí arákùnrin yi papòdà, o fe Ọba Adele Adéọ̀sun ní odún 1933 nígbàtí Tinubu be ìlú Abéòkuta wò ti a si fi ògùn fe. O télè Ọba yii de Ìlú Badagry ti o jẹ ibi ìfarapamó si fún àwọn Ọba àlàyé nìgbà naa.Nàíjírià Ní Ìlú Badagry yii bakan na a, o ló ipò ìyàwó Ọba tí o wa láti ta àwọn ojà ti o lòdì si èyí tí o ye ki o ta bii tòbákò, iyò àti òwò ẹrú.Ìya oba ni óbá oba ati ajélẹ̀ pẹ̀lú ẹfúnróyè parí ìjá ẹfúnróyè síì kúrò ìlú

Efunroye Tinubu (1810 – 1887), oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria.