Egbé Ọmọ Odùduwà

(Àtúnjúwe láti Egbe Omo Oduduwa)

Egbe Omo Oduduwa ni oruko egbe ti Obafemi Awolowo pelu awon alagba pataki ni ile Yoruba da sile ni odun 1945 ni ilu Londonu.