Eghajira
Eghajira jẹ́ ohun mímu tí ó dùn, ki, tí a ṣe láti ara àgbàdo àti èso, tí àwọn Tuaregs sábàá máa ń mu ní àkókò ayẹyẹ. Wọ́n sábàá máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú ìgbákọ.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Tuareg - Introduction, Location, Language, Folklore, Religion, Major holidays, Rites of passage, Relationships, Living conditions". Everyculture.com. Retrieved 2013-05-26.