Egungun tàbí egun tàbí eegun ni ìfun inú ara líle tó ṣe àpapọ̀ gbogbo egungun-ara àwọn ẹranko elégungun. Àwọn egun únṣe àbò fún orísi àwọn ìfun inú ara, wọ́n únṣẹ̀dá àwọn ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ pupa àti ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ funfun tí wọ́n jẹ́ àkóónú ẹ̀jẹ̀, wọ́n únṣe ìkópamọ́ àwọn ohun amọ́ralókun, wọ́n únṣe ọ̀nà-ìkọ́ àti ìmúdúró fún ara, wọ́n sì úngba ìmúrìn ní àyè.[1] [2] Àwọn egun wà bíi oríṣiríṣi. Ègún gùn wá ní oríṣiríṣi ìrísí, òsì ni orisirisi ìrísí nínú àti lóde. Wọn ṣe bẹ ní fuye síbè wọn lé gan wọn sì wá fún orisirisi ìṣe. Ègúngun tishoo (osseous tissue), ti atunle pé ní egungun nínú aileka nínú ọ̀rọ̀ yẹn, oje tishoo tó lè, oje nkan gbogi tón sọ tishoo papọ, ofe fara pé afara oyin nínú, tí ó ṣe iranlọwọ fún dídúró ṣinṣin. tishoo egungun, orisirisi èyín egungun lokorajo pò láàfin pé ní tishoo egungun.

Egun
A bone dating from the Pleistocene Ice Age of an extinct species of elephant.
A scanning electronic micrograph of bone at 10,000× magnification.
Identifiers
TAA02.0.00.000
THÀdàkọ:Str mid.html H3.01.00.0.00001
FMA5018
Anatomical terminology

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. PublBishing, Argosy. "Types of Bones - Learn Skeleton Anatomy". Visible Body. Retrieved 2019-06-06. 
  2. "Bones, Muscles, and Joints (for Parents)". KidsHealth. Retrieved 2019-06-06.