Ejegayehu Dibaba
Ejegayehu Dibaba Keneni ni a bini ọjọ kọkan leelogun, óṣu March, ọdun 1982 si Bekoji jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia[1][2].
Òrọ̀ ẹni | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Orúkọ ìbílẹ̀ | Ijigaayoo Dibaabaa | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Orúkọ àbísọ | እጅጋዬሁ ዲባባ | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kẹta 1982 Bekoji, Arsi Province, Derg | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Sport | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Sport of athletics | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Event(s) | Long-distance running | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeNi ọdun 2003, Dibaba kopa ninu ere ti gbogbo ilẹ Afirica ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura[3]. Ni ọdun 2004, Ejegayehu kopa ninu Olympics ti Athens ninu mita ti ẹgbẹẹrun mẹwa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver[4]. Ni ọdun 2005, Dibaba kopa ninu idije agbaye lori ere sisa ti mita ti ẹgbẹrun maarun to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ[5]. Ni ọdun 2010, Dibaba kopa ninu ere sisa ti kilo mita meje to wayr ni Memorial ti Peppe Greco to si gbe ipo keji. Ni ọdun 2011, Ejegayehu kopa ninu Marathon ti Chicago pẹlu wakati 2:22:09[6].