Ejgayehu Taye
Ejgayehu Taye ni a bini ọjọ kẹwa, Óṣu February, ọdun 2000 jẹ elere idaraya ti ọna jinjin ti órilẹ ede Ethiopia. Taye naa gba ami ọla ti idẹ fun 3000 metres ti idije agbaye ti inu ilè to waye ni ọdun 2022[1][2][3].
Òrọ̀ ẹni | |||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ethiopian | ||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kejì 2000 | ||||||||||||||||||
Sport | |||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | ||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Track and Field | ||||||||||||||||||
Event(s) | Long-distance running | ||||||||||||||||||
Achievements and titles | |||||||||||||||||||
Personal best(s) |
| ||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeNi óṣu July ọdun 2018, Ejgayehu Taye gba ami ọla ti ninu idije U20 IAAF agbaye ti 5000 metres. Ni ọdun 2019, Taye gbe ipo karun ninu ere ilẹ afirica ti 5000m[4][5].