Eko Hotels and Suites jẹ́ ilé ìtura onípele márún ní ìlú Èkó.[1][3][4][5]

Eko Hotels and Suites
Eko Hotels and Suites
Hotel chainEko Hotels & Resorts
General information
AddressOjúlé 1415 òpópónàn Adetokunbo Ademola , PMB 12724, Victoria Island, Ìlú Èkó, Nigeria
Coordinates6°25′21.108″N 3°25′37.927″E / 6.42253000°N 3.42720194°E / 6.42253000; 3.42720194Coordinates: 6°25′21.108″N 3°25′37.927″E / 6.42253000°N 3.42720194°E / 6.42253000; 3.42720194
Opening1977
ManagementChagoury Group
Other information
Number of rooms825[1]
Number of restaurants8[2]
Website
ekohotels.com

Àwọn ilé ounjẹ mẹ́jọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àti ilé ọtí mẹ́jọ ni ó wà ní ilé ìtura yìí.[2]

Ìtàn nípa rẹ̀

àtúnṣe
 
Eko Hotels & Suites Entrace

Wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 1977[6]Èkó Holiday Inn[7] atí wọ́n sì kọ́ọ sí Victoria Island, ó sì jẹ́ ilé ìtura tó tóbi jùlọ ní ìlú Èkó. Wọ́n yí orúkọ rẹ̀ sí Le Meridien Eko Hotel and Suites, Èkó. L'Hotel Eko Le Meridien jẹ́ ara ilé iṣẹ́ Chagoury Group.[8]

Kíkọ́ rẹ̀

àtúnṣe
 
Eko Hotels & Suites Exit

Ilé ìtura yìí ní yàrá bíi 825[1][9] sí ilé alájà mẹ́rin tí ó tóbi, wọ́n kùú ní funfun, òkun wa ní iwájú rẹ̀ àti etí ọsà Kùrámọ̀.[4] Wọ́n kọ́ ilé yìí sí ẹ̀gbẹ́ agbègbè ọrọ̀ ajé Lagos Island: Victoria Island, (tí ó jẹ́ agbègbè ibi ọjà títà àti ibùgbé) ṣùgbọ́n ó jìnà sí agbègbè aláriwo. Ilé ìtura yìí wà lẹ́gbẹ́ omi bí omi òkun Kùrámọ̀. Ibi tí wọ́n kọ sí yìí maa ń jẹ́ kí àwọn ènìyàn ní ààǹfàní láti wo òkun àti àyìká tí ó jẹ́ kí wọ́n maa ń pèé níEnvironment of Aquatic Splendour.[3] Àwọn ohun ìgbàlódé tí ó wà ní ilé ìtura yìí maa ń jẹ́ kí àwọn ènìyàn láànfàní sí àwọn ilé iṣẹ́ ńláńla.

Àwọn ayẹyẹ

àtúnṣe

Eko Hotels and Suites ní àyè tí ó tóbi fún àyẹyẹ tí ó sì tóbi jùlọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[10][11] Àwọn ayẹyẹ tí wọ́n ti ṣe níbẹ̀ ni àjọ̀dún orin, ìṣàgbéjáde eré, ìṣàfihàn iṣẹ́ ọnà, ayẹyẹ ìgbeyàwó[12] àti ayẹyẹ bíi Africa Magic Viewers Choice Awards, Africa Movie Academy Awards, AGRIKEXPO, àti oríṣiríṣi ìṣàfihàn ọlọ́dọọdún bí  Lagos Photo Festival. Wọ́n maa ń lo ibẹ̀ fún ayẹyẹ yìí tí ó sì lè gba àwọn ènìyàn bíi ẹgbẹ̀rú mẹ́fà.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Eko Hotels builds Signature with N2.5bn". The Vanguard. December 10, 2013. http://www.vanguardngr.com/2013/12/eko-hotels-builds-signature-n2-5bn/. Retrieved April 4, 2016.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "vanguard" defined multiple times with different content
  2. 2.0 2.1 Adeleke Ajayi (November 4, 2014). "Eko Hotel to build more restaurants, says official". News Agency of Nigeria. Archived from the original on November 15, 2014. https://web.archive.org/web/20141115091418/http://www.nannewsnigeria.com/eko-hotel-build-more-restaurants-says-official. Retrieved April 4, 2016.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "nan" defined multiple times with different content
  3. 3.0 3.1 African Cities Driving the NEPAD Initiative. UN-HABITAT, 2006. p. 258. ISBN 9789211318159. https://books.google.com.ng/books?id=tk5TP7bsXnkC&pg=PA258&dq=Lagos+City+Hall&hl=en&sa=X&ved=0CCMQ6AEwAWoVChMI9fH30Y7ZyAIVBdUeCh2TtgbC#v=onepage&q=eko%20hotel&f=false. 
  4. 4.0 4.1 4.2 Angela Uponi (2007). Handbook on tourism and hospitality in southwestern Nigeria. GSL Publishers. https://books.google.com.ng/books?id=Q-4uAQAAIAAJ&q=eko+hotels+and+suites&dq=eko+hotels+and+suites&hl=en&sa=X&ei=3khpVaLyBcWp7Ab7g4CQCA&ved=0CCsQ6AEwAQ. Retrieved May 4, 2015. 
  5. Angela Uponi (2007). Handbook on tourism and hospitality in southwestern Nigeria. GSL Pub. p. 69. https://books.google.com.ng/books?id=Q-4uAQAAIAAJ&q=C. 
  6. Kaye Whiteman (2013). Lagos: A Cultural and Literary History Volume 5 of Landscapes of the Imagination. Andrews UK Limited. ISBN 978-1-908-4938-97. https://books.google.com.ng/books?id=fcS_BAAAQBAJ&pg=PT109&dq=Eko+Hotels+and+suites+Lagos&hl=en&sa=X&ei=44-NVaCzFcaX7Qa-5YnQDw&ved=0CF0Q6AEwCQ#v=onepage&q=Eko%20Hotels%20and%20suites%20Lagos&f=false. 
  7. The African Guardian. Guardian Magazines. 1990. p. 38. https://books.google.com.ng/books?id=ASwuAQAAIAAJ&q=eko+hotels+and+suites+Nigeria%27s+largest+hotel&dq=eko+hotels+and+suites+Nigeria%27s+largest+hotel&hl=en&sa=X&ved=0ahUKEwjH4vq7g_rLAhVKaRQKHYFZDAcQ6AEINzAE. Retrieved April 6, 2016. 
  8. "Tinubu visits Gilbert Chagoury over first son's death in Paris". News of the people. http://www.newsofthepeople-ng.com/tinubu-visits-gilbert-chagoury-over-first-sons-death-in-paris/. Retrieved April 6, 2016. 
  9. Justina Ikoanu (April 18, 2014). "Fashola hails job-creating potential of Eko Hotel, tourism". Newswatchtimes. Archived from the original on April 15, 2016. https://web.archive.org/web/20160415215557/http://www.mynewswatchtimesng.com/fashola-hails-job-creating-potential-eko-hotel-tourism/. Retrieved April 4, 2016. 
  10. Demola Ojo (October 21, 2012). "Nigeria: Eko Hotel's Attraction". AllAfrica. http://allafrica.com/stories/201210210247.html. 
  11. "THE TOP FIVE MOST EXPENSIVE EVENT VENUES IN LAGOS". Encomium. April 6, 2015. http://encomium.ng/the-top-five-most-expensive-event-venues-in-lagos/. Retrieved April 3, 2016. 
  12. Justina opanku (April 19, 2013). "Eko Hotel opens door to art world". Newswatchtimes. Archived from the original on April 17, 2016. https://web.archive.org/web/20160417062816/http://www.mynewswatchtimesng.com/eko-hotel-opens-door-to-art-world/.