Ekuro Ope
Ekuro Ope je eso igi ope. Lara eso yii ni a ti maa n se epo pupa ati epo adi-soso.[1] Awo pipon ara eso yii ti a mo si eyin-ekuro [2] ni a ti n ro epo pupa, ekuro inu re ni a ti a ro epo adi-soso.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Palm Kernel Oil - an overview". ScienceDirect Topics. 2016-01-01. Retrieved 2019-09-23.
- ↑ "Oil palm - tree". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-09-23.
- ↑ "2 OIL PALM". Home | Food and Agriculture Organization of the United Nations. Retrieved 2019-09-23.