Ekwang

Oúnjẹ ìbílẹ̀ ti àwọn ará Efik àti Ibibio ní Nàìjíríà

Ekwang (tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí "Ekpang Nkukwo" ní èdè “Efik”, "Ekpang" ní èdè “Ibibio/Annang” àti "Ekwang Coco") jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ Cameroon àti Nàìjíríà èyí tí ó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ènìyàn ní Bakweri, Bafaw, Oroko, Ìpínlẹ̀ Cross River àti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.[1][2] Iṣu kókó tí wọ́n rìn tí wọ́n wá fi ewé kókó wé ni wọ́n fi máa ń se oúnjẹ yìí.[3][4] Àwọn èròjà mìíràn ni ẹja yíyan tàbí ẹja gbígbẹ, ẹran, epo, edé, Periwinkle àti èròjà ìsebẹ̀.[5]

Ekwang

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "HOW TO MAKE DELICIOUS EKWANG". Precious Core (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-14. Retrieved 2021-07-18. 
  2. Abella, Heidi. "Cameroon Ekwang by PreciousKitchen". African Vibes Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-18. 
  3. "My Local Adventures Blog: The Best Ekwang Recipe in Cameroon". My Local Adventures Blog. Retrieved 2021-07-18. 
  4. "Ekwang (Ekpang Nkukwo)". Immaculate Bites (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-12-27. Retrieved 2022-03-05. 
  5. "Ekwang | Traditional Stew From Southwest Region | TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 2022-03-05.