Elbridge Gerry

Olóṣèlú

Elbridge Gerry (July 17, 1744 – November 23, 1814) jẹ́ olóṣèlú àti gbajumọ olú ṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà àti ẹlẹẹkarun-un Igbakeji Ààrẹ Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀, ni abẹ́ ààrẹ James Madison no ọdún 1813 títí dii ọjọ́ ikú rẹ̀ níí ọdun 1814.

Elbridge-gerry-kíkùn