Agbèègbè ìdìbò ti Paddington (Queensland)
(Àtúnjúwe láti Electoral district of Paddington (Queensland))
Agbèègbè ìdìbò ti Paddington jẹ́ tí àwọn tí ó lẹ̀tọ́ làti dìbò fún aṣojú ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ti ìpínlẹ̀ Queensland, Australia.[1]
Ìtàn
àtúnṣeWọ́n dá Paddington sílẹ̀ ní ọdún 1911 lẹ́yìn àtúnpín ìlú, tí o sẹlẹ̀ ní ọdún 1912 nínú ìdìbò ìpínlẹ̀, agbèègbè ìdìbò yí wà títí dì ọdún 1932 ní àkókò ìdìbò ìpínlẹ̀.[1] Orisun awon agbegbe re je ni Brisbane North èyí tí o parun nínú ìdìbò 1912.[1]
Nígbàtí Paddington parun ní ọdún 1932, àwọn agbègbè rẹ̀ dàpọ̀ mọ́ agbèègbè Brisbane ati Baroona.[1]
Àwọn aṣojú
àtúnṣeÀwọn enìyàn wọ̀nyí ní wón ìdìbò yàn gẹ́gẹ́ bí aṣojú Paddinton :[1][2]
Aṣojú | Ẹgbẹ́ òṣèlú | Ìgbà | |
---|---|---|---|
John Fihelly | Labor | 27 Apr 1912 – 7 Feb 1922 | |
Alfred James Jones | Labor | 18 Mar 1922 – 11 Jun 1932 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "Representatives of Queensland State Electorates 1860 - 2012" (PDF). Queensland Parliament. Retrieved 31 January 2014.
- ↑ "Alphabetical Register of Members of the Legislative Assembly 1860-2012 and of the Legislative Council 1860-1922" (PDF). Queensland Parliament. Retrieved 31 January 2014.