Elijah Abina
Elijah Oludele Abina(bi i Okudu 16, 1935) je pasito ati Agba Aguntan ti The Gospel Faith Mission International (GOFAMINT).[1]
Elijah Oludele Abina | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹfà 1935 Aradagun, Badagry Ipinle Eko Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Papa Abina or Pastor Abina or Daddy GO |
Iṣẹ́ | Clergyman |
Olólùfẹ́ | Matron Felicia Abina (nee Akinremi) (m. 1961) |
Ibere aye
àtúnṣeElijah Ogundele Abina ti wo bi sinu ile Pa Abraham Akowanu Abina ni Aradagun, Badagry Ipinle Eko[2]
Aye ara eni
àtúnṣePastor Abina gbe Felicia Abina ni iyawo ni Osu Keta Ojo 30, Odun 1966. Papo, won ni omo mefa, ti won je Folorunsho, Olabisi, Funmilayo, Ebunoluwa, Gbenga ati Femi. Matron Felicia Abina ku ni Osu Kefa Odun 2014.[3][4]
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Why Nigeria has not disintegrated, by Pastor Abina, PFN founding father". Vanguard News. 2016-10-09. Retrieved 2022-02-25.
- ↑ International, The Gospel Faith Mission. "Our Story – The Gospel Faith Mission International" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-15.
- ↑ Okonoboh, Rita (2017-07-30). "We have lived together too long to disintegrate —Pastor (Dr) Abina, General Overseer, GOFAMINT". Tribune Online. Retrieved 2022-02-25.
- ↑ Odebiyi, Olatunde (2014-09-12). "Exit of a ‘virtuous’ woman". The Nation Newspaper. Retrieved 2022-02-25.