Elizabeth Cudjoe
Elizabeth Cudjoe jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 17, óṣu october ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin Hasaacas gẹgẹbi forward[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 17 Oṣù Kẹ̀wá 1992 | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Hasaacas Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | 6 | (3) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Elizabeth kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].