Ellen Coleman jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 11, óṣu December ni ọdun 1995. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin strikers gẹgẹbi defender[1].

Ellen Coleman
Personal information
Ọjọ́ ìbí11 Oṣù Kejìlá 1995 (1995-12-11) (ọmọ ọdún 29)
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Lady Strikers
National team
2017-18Ghana women's national football team2(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 16 June 2019

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Ellen kopa ninu Cup awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2018[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/ellen-coleman_prs332015/person.shtml
  2. https://ng.soccerway.com/players/ellen-coleman/151529/