Emina Ilhamy
Emina Ilhamy (Lárúbáwá: امینه الهامی; ọjọ́ kẹrìnlẹ́lógún oṣù 1858 – ọjọ́ kàn dínlógún oṣù kẹ́fà ọdún 1931)[1] tí àwọn míràn mọ̀ sí Amina Ilhami, jẹ́ ọmọbabìnrin Ìjíptì àti ọmọ ìran Muhammad Ali Dynasty. Òun ni Khediva àkọ́kọ́ ní Íjíptì láti 1879 títí di 1892, gẹ́gẹ́ bí ìyàwó Khedive Tewfik Pasha. Lẹ́yìn ikú Khedive Tewfik, ó di Walida Pasha ọmọ wọn, Khedive Abbas Hilmi II láti 1892 sí 1914.[2]
Emina Ilhamy | |
---|---|
Nineteenth century photograph | |
Khediva consort of Egypt
| |
Tenure | 25 June 1879 – 7 January 1892 |
Predecessor | Title created |
Successor | Ikbal Hanim |
Walida Pasha of Egypt
| |
Tenure | 8 January 1892 – 19 December 1914 |
Predecessor | Shafaq Nur Hanim |
Successor | Title abolished |
Spouse | Tewfik Pasha
(m. 1873; died 1892) |
Issue | |
| |
Full name | |
Lárúbáwá: امینه الهامی Àdàkọ:Lang-tr | |
House | Muhammad Ali |
Father | Ibrahim Ilhami Pasha |
Mother | Nasrin Qadin |
Born | Constantinople (now Istanbul), Ottoman Empire | 24 Oṣù Kàrún 1858
Died | 19 June 1931 Bebek, Bosphorus, Istanbul, Turkey | (ọmọ ọdún 73)
Burial | Qubbat Afandina, Khedive Tawfik Mausoleum, Kait Bey, Cairo, Egypt |
Religion | Sunni Islam |
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Emina Ilhamy ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1858 ní Constantinople (ibi tí a wá mọ̀ sí Istanbul).[3] Ó ni ọmọbìnrin àkọ́kọ́ Lieutenant General Prince Ibrahim Ilhami Pasha[4] àti ìyàwó rẹ̀, Nasrin Qadin (tí ó fayé sílẹ̀ ní ọdún 1871).[5] Ó ní arábìnrin méjì,[6] Ọmọbabìnrin Zeynab Ilhamy àti Ọmọbabìnrin Tevhide Ilhamy.[7] Ọmọbabìnrin Zeynab fẹ́ Mahmud Hamdi Pasha, ọmọkùnrin karùn-ún Isma'il Pasha[8] àti Jihan Shah Qadin.[9] Ó jẹ́ ọmọ-ọmọ Abbas I àti Mahivech Hanim.[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ekrem Buğra Ekinci - İHTİŞAMIYLA İSTANBul'u IŞILDATAN BİR VÂLİDE PAŞA VARDI…".
- ↑ Aboelmagd, Amal (2021). "Amina Hanim Elhami (Valide Pasha) Palace at Istanbul City - Historical Architectural study". Journal of Association of Arab Universities for Tourism and Hospitality 21 (5): 241–259. https://jaauth.journals.ekb.eg/article_206844.html.
- ↑ "His Highness Hidiv Mehmet Tevfik Paşa, Hidiv of Misir (Egypt), Sudan and Taşoz". Retrieved 23 May 2019.
- ↑ Houtsma, Martijn Theodoor (1993). E. J. Brill's First Encyclopaedia of Islam: 1913–1936. Brill Publishers. pp. 1118. ISBN 978-9-00-409796-4.
- ↑ Catalogue of the Abbas Hilmi II Papers. Durham University Library. 2020. pp. 333.
- ↑ Malortie, Karl Von (1882). Egypt: Native Rulers and Foreign Interference. W. Ridgway. pp. 300–301.
- ↑ İstanbul su külliyâtı: Vakıf su defterleri: Bogazici ve Taksim sulari 2 (1813-1928). 1997. pp. 83. ISBN 978-9-758-21504-1.
- ↑ Cuno 2015, p. 37.
- ↑ 9.0 9.1 Doumani 2003, p. 270.