Emmanuel Eni tí a mọ̀ sí Blackman ni European Kitchen ni a bí ní ọdún 1967. [1] Ó jẹ́ olórin àti akéwì orílẹ̀-èdè Jamaní tí a bí sí Nàìjíríà. A mọ̀ ọ́n bí i olùyàwòrán, agbẹ́gilére, olórin, àti akéwì. Iléeṣẹ́ ìwé ìròyìn THE NATION ṣàpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn ayàwòrán tó tayọ, lọ́lá jùlọ lágbàáyé. Láìpẹ́, Forbes ṣe àfihàn rẹ̀ bí i ọ̀kan lára àwọn oníṣẹ́-ọnà tó gbajúmọ̀ àti tó lókìkí jùlọ̀ ní ọdún 2020. Eni Emmanuel, tí ó jẹ́ olókìkí fún ọkàn àìníbẹ̀rù rẹ̀, wíwá-ọkàn, iṣẹ́-ọnà ìmọ̀-ìjìnlẹ̀, ni a ṣe àpèjúwe bí i àmì ti ìpín tí kò wọ́pọ̀ https://thenationonlineng.net/how-germany-based-nigerian-artist-turned-lockdown-to-creative-forge / . [2] [3] [4]

Emmanuel Eni

Ìgbésíayé e rẹ̀

àtúnṣe

A bí Emmanuel Eni ní ọdún 1967 ni ìlú Igbanke ní orílèdè Nàìjíríà. Ó kọ́ nípa iṣẹ́-ọnà ní ilé-ẹ̀kọ́ Igbobi College ní ìlú Èkó; Ilé-ẹ̀kọ́ giga Polytechnic ti Auchi; àti ní Yunifásitì ti Benin. Ní káriáyé, Eni ṣe àfihàn ní Biennale d'art contemporain de Lyon, Biennale ní Dakar (Dak'Art) [1] àti ní ṣíṣe àfiwé, pẹ̀lú ni documenta12 ní Kassel. Ó tún ṣiṣẹ́ bí i olùkọ́ni ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládàáni àti ti gbogboogbò. Ó jẹ òǹkọ̀wé àti òṣèré ti "Blackman in European Kitchen" àti pé a tún mọ̀ ọ́n gẹ́gẹ́ bí i "sculptor of elephants" àti "Father of 100 Elephants".

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help) 
  3. Empty citation (help) 
  4. Empty citation (help)