Emmanuel Aobwede Eseme (ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kejo ọdun 1993) je elere ije orile-ede Cameroon. O dije ninu mita 200 awọn ọkunrin ni Idije ere-idaraya Agbaye ti 2019 ti o waye ni Doha, Qatar. [1] O ko pe lati dije ninu ologbele-ipari. [1]

Ni ọdun kanna, o tun dije ninu mita 200 ọkunrin ati ìdíje 4 × 100 awọn ọkunrin ni Awọn ere Afirika laisi gbigba ami-eye kankan ninu ìdíje mejeeji. [2]

O ṣe aṣoju orilẹ-ede Cameroon ni Olimpiiki Igba ooru 2020 ni Tokyo, Japan ni mita 200 ti awon ọkunrin.

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help) 

Ita ìjápọ

àtúnṣe