Emmerson Mnangagwa
Emmerson Dambudzo Mnangagwa (IPA: [m̩.na.ˈᵑɡa.ɡwa], US: ( listen); ọjọ́ìbí 15 September 1942) ni olóṣèlú ará Zimbabwe àti Ààrẹ ilẹ̀ Zimbabwe láti 24 November 2017. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olóṣèlú ZANU–PF àti igbákejì ààrẹ sí Ààrẹ Robert Mugabe.