Emmanuel Nwankwo, tí a tún mọ̀ sí Emmy Gee, jẹ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè South Africa. Orin àdákọ àkọ́kọ́ rẹ̀ "Rands and Nairas" wà nípò keje láàárín àwọn orin orí àtẹ ní ilẹ̀ South Africa.[2] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gba orin sílẹ̀ nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́rìndínlógún, ó sì í ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Shizzi n ọdún 2004. Ó jùmọ̀ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ kan, tí wọ́n ń ṣe ohun ìdánilárayá àti aṣọ tí a mọ̀ Teamtalkless.[1][3]

Emmy Gee
Orúkọ àbísọEmmanuel Nwankwo[1]
Ọjọ́ìbí10 Oṣù Kẹjọ 1986 (1986-08-10) (ọmọ ọdún 38)
Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Johannesburg, South Africa
Irú orinHip hop
Occupation(s)
  • Rapper
  • singer
  • entrepreneur
Years active2013–present
LabelsTeamtalkless
Associated acts
  • AB Crazy
  • DJ Dimplez
  • King Jay

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti orin àkọ́kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Emmy Gee sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ẹ̀yà Ibo. Òun ni àbígbẹ̀yìn láàrin àwọn ọmọ mẹ́rin. Ó ṣe àṣeparí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní Naijiria kí ó tó kó lọ sí ilẹ̀ South Africa. Wọ́n ṣe ìgbéjáde orin àdákọ alákọ̀ọ́kọ́ Emmy Gee "Rands and Nairas" ní ọdún 2013.

Àtòjọ orin rẹ̀

àtúnṣe

Orin àdákọ

àtúnṣe
List of singles as featured artist, with selected chart positions, showing year released and album name
Title Year Peak chart positions Album
SA
"Rands and Nairas"
(featuring AB Crazy and DJ Dimplez)
2013 7 TBA
"Rands and Nairas (Remix)"
(featuring Ice Prince, AB Crazy, Anatii, Phyno, Cassper Nyovest and DJ Dimplez)
2014
"Champagne Showers"
(featuring King Jay)
2015

Gẹ́gẹ́ bíi àfifún olórin

àtúnṣe
Artist Title Year Peak chart positions Album
SA
Buffalo Souljah "Ziyawa" (featuring. Red Button & Emmy Gee) 2014 The Chosen One
Bolo J "This Year" (featuring. Emmy Gee) 2015 Non-album singles
DJ Dimplez "Bae Coupe" (featuring. Ice Prince, Emmy Gee & Riky Rick)
DJ Scratch Masta "To the Tope" (featuring. Emmy Gee, AB Crazy & Eindo) 2016
King Jay "Owami" (featuring. Emmy Gee)
Tkinzy "Shake Ikebe" (featuring. Emmy Gee)
Teamtalkless "Church" (featuring. DJ Dimplez, TRK, Emmy Gee & King Jay) [4] 2017
DJ Kaywise "Normal Level" (featuring. Ice Prince, Kly & Emmy Gee) 2018 Àdàkọ:TBA

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe
Year Awards ceremony Award description(s) Recipient Results Ref
2014 Nigeria Entertainment Awards Best Music Video of the Year (Artist & Director) "Rands and Nairas" Gbàá [5]
Diaspora Artist of the Year Himself Wọ́n pèé [6]
Channel O Music Video Awards Most Gifted Newcomer Wọ́n pèé [7]
Most Gifted Video of the Year "Rands and Nairas" Wọ́n pèé
2015 Nigeria Entertainment Awards Diaspora Artist of the Year "Himself" Wọ́n pèé [8]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "EMMY GEE Biography". MTV Base. Archived from the original on 28 July 2014. Retrieved 26 July 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "AIRPLAY CHART". EMA. Archived from the original on 29 April 2014. Retrieved 26 July 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "EMMY GEE: SPENDING RANDS AND NAIRAS". Zalebs. Archived from the original on 26 July 2014. Retrieved 26 July 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Solanke, Abiola. "Teamtalkless "Church" ft DJ Dimplez, TRK, Emmy Gee, King Jay". Pulse Nigeria. Archived from the original on 19 August 2017. Retrieved 19 August 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Nigerian Entertainment Awards; Full List of Winners". Daily Times of Nigeria. 1 September 2014. Archived from the original on 22 October 2014. Retrieved 2 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Abimboye, Micheal (31 May 2014). "Pop duo, Skuki, reject Nigerian Entertainment Awards nomination". Premium Times. Archived from the original on 5 June 2014. Retrieved 1 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Marshall, Rhodé (5 September 2014). "Channel O Africa announces Music Video Awards nominees". Mail & Guardian. Archived from the original on 13 September 2014. Retrieved 12 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Olayinka, Obey (7 September 2015). "See Moments From The 10th NEA Awards And List Of Winners [PICTURES]". Naij. Archived from the original on 21 August 2016. Retrieved 19 August 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)