Emperor Ninmyō je Obaluaye Japan tele. Oba Nimyo ( orukọ lẹkunrẹrẹ, Nimuyo-tenno, Abi ni ojo ketadinlogbon osu kẹsán odun 808 osi di ologbe ni ọjọ kefa osu karun odun 850)[1] jẹ ọba kerinle ni àádọta ni ilu Japani [1] gẹgẹ bíi iṣe Asa ifọbajẹ ilu naa. Ojọba lati odun 833 sí ọdún 850 ni akoko ti Heian.

Emperor Ninmyō


Itokasi àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "Emperor Ninmyō". Wikipedia. 25 Feb 2002. Retrieved 3 Mar 2022.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Wikipedia 2002" defined multiple times with different content