Endurance Abinuwa
Endurance Abinuwa (tí wọ́n bí ní 31 July 1987) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ eléré-ìdárayá tó máa ń sáré. Ó kópa nínú ìdíje 2012 Summer Olympics.[1]
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọjọ́ìbí | 31 Oṣù Keje 1987 Sapele, Nigeria |
Height | 1.59 m (5 ft 3 in) |
Weight | 54 kg (119 lb) |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Athletics |
Event(s) | 400 metres |
College team | UTEP |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Endurance Abinuwa". UTEP Miners. Retrieved 2024-04-08.