Eniola Badmus

Òṣéré orí ìtàgé

Eniola Badmus, (tí a bí ní Oṣù Kẹ̀sán Ọjọ́keje, Ọdún 1983),[1] òṣèré fíìmù ti Ilu Nàìjíríà . [2] Arábìnrin náà bẹ́ẹ̀ sí ní òkìkí ní ọdún 2008, lẹ́hìn tí o ṣe ìfihàn nínu fiimu Jenifa . [3]

Eniola Badmus
Eniola
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹ̀sán Ọjọ́keje, Ọdún 1983
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́Theatre Arts
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásítì ti Ìbàdàn
Yunifasiti ti Ipinle Eko
Iṣẹ́òṣèré

Eniola jẹ́eẹni bíbí ìlú Èkó ní Nàìjíríà. Ó ní ẹkọ ìpìlẹ̀ àti ilé-ìwé gíga ní Ìjẹ̀bú Òde[4].Ó lọ sí Yunifásítì ti Ìbàdàn ní biti ó ti kẹ́kọ̀ọ́ Theatre Arts.Ó gba oyè M.Sc nínu Ìṣòwò ní Yunifasiti ti Ipinle Eko[5].

Àparapò Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. http://dailytimes.ng/much-ado-about-eniola-badmus-real-age/
  2. http://www.vanguardngr.com/2015/01/average-man-without-body-mouth-odour-eniola-badmus/
  3. https://www.naij.com/70215.html
  4. http://biographyroom.com/eniola-badmus-biographyagemovies-profile/
  5. http://thenet.ng/2015/09/eniola-badmus-10-quick-facts-about-your-favourite-plus-size-actress/