Ephraim Akpata
Ephraim Ibukun Akpata | |
---|---|
Alága àkọ́kọ́ Independent National Electoral Commission | |
In office 1998 – January 2000 | |
Asíwájú | Sumner Dagogo-Jack |
Arọ́pò | Abel Guobadia |
Justice of Supreme Court | |
In office 1993 – Unknown | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 April 1927 Edo State |
Aláìsí | 8 January 2000 | (ọmọ ọdún 72)
Aráàlú | Nigerian |
Ephraim Omorose Ibukun Akpata (wọ́n bí lọ́jọ́ 15 oṣù April ọdún 1927 – ọjọ́ 8 oṣù January ọdún 2000) jẹ́ Adájọ́-àgbà ilé-ẹjọ́ tó ga jù lọ Nigeria, Supreme Court of Nigeria àti alága àkọ́kọ́ tí Independent National Electoral Commission (INEC) ní Nigeria, òun ni ó ṣe ètò ìdìbò ọdún 1998/1999 tí wọ́n bí àtúnbẹ̀rẹ̀ ìjọba àwararawa ní Nigeria l'óṣù June ọdún 1999.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Jude Opara (2 June 2009). "INEC 10 Years After – an Appraisal". Daily Champion. Retrieved 13 February 2010.