Epo Rọ̀bì
Bẹntiróò (/pəˈtroʊliəm/) jẹ́ ọ̀kan lára ohun àlùmọ́nì kan tí ó ní àwọ̀ méjì àwọ̀ dúdú àti omi ará yẹ́lò tí wọ́n ma ń wà jáde lábẹ́ ilẹ̀.[1] Wọ́n ma ń fe ohun àlùmọ́nì yí sí oríṣiríṣi ọ̀nà, ní èyí tí a ti rí Epo Bẹntiróò àti àwọn mìíràn. Wọ́n ma ń ṣàdáyanrí oríṣiríṣi epo sọ́tọ̀ láti ara bẹtiróò nípa lílo ohun tí eọ́n ń pe ní (fractional distillation).[2][3] Lára bẹntiróò ni wọ́n ti ma ń yọ Epo Karosíìnì, asphalt àti kẹ́mìkà tí wọ́n ń pe ní reagent tí wọ́n ń lò láti fi pèsè àwọn ike, àti ògùn kòkòrò oríṣiríṣi.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "EIA Energy Kids – Oil (petroleum)". www.eia.gov. Archived from the original on July 7, 2017. Retrieved March 18, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "A permeability model for naturally fractured carbonate reservoirs". Marine and Petroleum Geology 40: 115–134. 2012. Bibcode 1990MarPG...7..410M. doi:10.1016/j.marpetgeo.2012.11.002.
- ↑ "Improved statistical multi-scale analysis of fractures in carbonate reservoir analogues". Tectonophysics 504 (1): 14–24. 2011. Bibcode 2011Tectp.504...14G. doi:10.1016/j.tecto.2011.01.003.
- ↑ "Organic Hydrocarbons: Compounds made from carbon and hydrogen". Archived from the original on July 19, 2011.
- ↑ Intergovernmental Panel on Climate Change. "Climate Change 2014 Synthesis Report." p. 56 (https://ar5-syr.ipcc.ch/ipcc/ipcc/resources/pdf/IPCC_SynthesisReport.pdf[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́])