Eré Ìgbéyàwó jẹ́ eré fún àwọn olukopa méjì nípasẹ̀ Edward Albee. Eré ìdáni lára yá náà bẹ̀rẹ̀ ní gbọ̀ngàn Tíátà tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ní Vienna ní ọdún 1987.

Àwọn àkójọpọ̀ iṣẹ́ àtúnṣe

Àgbéjáde Eré Ìgbéyàwó fún ìgbà àkọ́kọ́ wáyé ní ọjọ́Kẹtàdílógún oṣù Kárùún, ọdún 1987 ní gbọ̀gàn Tìátà tiàwọn Gẹ̀ẹ́sì ní Vienna. Ìfilọ́lẹ̀ eré náà wáyé láti ọwọ́ Tíátà ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn Òṣèré tí ó kópa nínú eré náà ni Kathleen Butler gẹ́gẹ́ bí (Gillian) àti Tom Klunis gẹ́gẹ̀ bí (Jack). [1] [2]

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. Albee, Edward. "Iṣaaju", Igbadun Igbeyawo Alẹwa Edward Albee, Dramatists Play Service Inc, 1995,
  2. "Archive, 1987" Error in webarchive template: Check |url= value. Empty. englishtheatre.at, accessed November 22, 2015