Eré ọmọdé
Eré ọmọdé Gbogbo ọmọdé ní orílẹ̀-ayé ni o fẹran eré ṣíṣe nínú ilé,nínú ọgbà, ní àdúgbò àti ní ìgbro. Ọmọdé a maa ba gbogbo ènìyàn ṣiré tàbí ki o jáde láti bá ẹlẹgbẹ rẹ̀ ṣiré ni àdúgbò kan naa. Inú dídùn àti ẹ̀rín jẹ́ àmì eré ṣiṣe laarin ọmọdé àti àgbà.[1] Akọ́mọlédè ìjìnlẹ̀ Yorùbá vol 1
Oríṣiríṣi eré ọmọdé
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ ISBN 978 132 213 6