Erékùṣù Robben (Geesi: Robben Island; Afrikaans Robbeneiland) je erekusu ni Table Bay, to je kilomita meje leba Cape Town, ni Guusu Afrika. O je ede Dọ́tsh fun "seal island". Erekusu Robben ri bi oval, 3.3 km gigun lati ariwa de guusu, ati 1.9 km ni fife, pelu aala to je 5.07 km².[1] Pelebe ni, o si je bi mita melo soke ipele omi-okun, nitori agbara-omi to sele nigba ijoun. O kun fun awon okuta ateyinda igba Atetesi Kambria ninu Adipo Malmesbury Group. Erekusu yi se pataki nitoripe ibe ni Aare ile Guusu Afrika ojowaju ati Elebun Nobel Nelson Mandela ati Aare ile Guusu Afrika ojowaju Kgalema Motlanthe,[2] bakanna mo awon elewon oloselu miran, ti lo igba ewon won ni asiko apartheid. Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika tẹlẹ na lo odun mewa nibe bi elewon.

Erékùṣù Robben
Robben Island
*
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO


Prison buildings on Robben Island. Table Mountain is visible 15 km in the background
State Party  Gúúsù Áfríkà
Type Cultural
Criteria iii, vi
Reference 916
Region** Africa
Coordinates 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°E / -33.806734; 18.366222Coordinates: 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°E / -33.806734; 18.366222
Inscription history
Inscription 1999  (23rd Session)
* Name as inscribed on World Heritage List.
** Region as classified by UNESCO.




  1. "?". 
  2. "New S. Africa president sworn in". BBC News. 2008-09-25. Retrieved 2008-11-22.