Nígbà tí a bá pá ajá, àwọn ọ̀wọ́ ènìyàn kan wà ní ilé Yorùbá tí wọn a má jẹ́ ajá yálà fún ìgbádún, ìpanu tàbí fún oúnjẹ ilé. Léyìn tí wón bá Pá Ajá tan, wọn á ge, lẹyìn náà ní wọn má ń Yan ẹran rẹ fún jíjẹ tàbí fún títà.

Ẹran ajá


Ọ tún le ka àtúnṣe