Eric Arturo Delvalle (Ọjọ́ kejì Oṣù kejì Ọdún 1937 - Ọjọ́ kejì Oṣù kẹwá Ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ará Panama. Ó jẹ́ igbákejì ààrẹ lábẹ́ Nicolás Ardito Barletta. Lẹ́yìn tí wọ́n fagilé ètò ìdìbò ọdún 1984, tí Barletta fi ipò sílẹ̀, Delvalle di ààrẹ̀ Panama láti Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹsán Ọdún 1985 di ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀ Oṣù kejì ọdún 1988.[1][2]

Eric Arturo Delvalle

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. William Branigan (28 February 1988). "Panama's President In Hiding; Delvalle Flees Home As Military Orders His Expulsion". Washington Post. HighBeam Research. Archived from the original on 25 February 2016. Retrieved 30 September 2012. 
  2. Glenn J. Antizzo (2010). U.S. military intervention in the post-Cold War era : how to win America's wars in the twenty-first century. Baton Rouge: Louisiana State University Press. pp. 43. ISBN 978-0-8071-3642-3.