Eru (ọbẹ̀)
Eru jẹ́ ẹ̀fọ́ ní ilẹ̀ Cameroon. Ó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ènìyàn Bayangi, tó wà ní agbègbè Manyu, ní apá Gúúsù mọ́ Ìwọ̀-oòrùn Cameroon. Ó jẹ́ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ tí wọ́n fi ewé eru tàbí okok sè. Wọ́n máa ń fi gbúre tàbí efinrin, epo, edé, ẹjá yíyan, pọ̀nmọ́ tàbí ẹran se ewé eru yìí.
Wọ́n máa ń fi fùfú tàbí gaàrí jẹ oúnjẹ yìí.
Eru Recipe
-
Arábìnrin tó ń gé ewé erú
-
Sísè
-
Ewé eru fún títà
-
Edé tí wọ́n fi ń se erú
-
Ẹ̀gé tí wọ́n fi ń ṣe fùfú
-
Gaàrì náà ṣe é fi jẹ́ ọbẹ̀ eru
-
"Canda" ni wọ́n ń pe pọ̀nmọ́ tí wọ́n ń fi sínú ọbẹ̀ eru
-
Oúnjẹ ti délè! fufu àti ọbẹ̀ Eru
-
Pọ̀nmọ́ nínú ọbẹ̀ eru
-
Pákí tútù
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- Grubben, G.J.H. (2004). Vegetables. Plant resources of tropical Africa. PROTA Foundation. p. 520. ISBN 978-90-5782-147-9. https://archive.org/details/bub_gb_6jrlyOPfr24C.