Esse Akida jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 18, óṣu november ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa lọwọ ṣere fun POAK ni ilẹ greece, o wa lara awọn ọmọ ẹgbẹ Harambee Starlets[1][2][3].

Esse Akida
Personal information
OrúkọEsse Mbeyu Akida
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kọkànlá 1992 (1992-11-18) (ọmọ ọdún 32)
Ibi ọjọ́ibíKilifi, Kenya
Playing positionForward
Club information
Current clubThika Queen's
Number14
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Spedag
2018Thika Queens FC
2018–2019F.C. Ramat HaSharon22(4)
2020Beşiktaş J.K.2(0)
2021-P.A.O.K. F.C. (women)2(3)
National team
2012–Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 23 February 2021. † Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Esse kopa ninu Nations Cup awọ̀n obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2016 ati 2018 nibi ti o ti jẹ aṣoju fun ilẹ kenya[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.uefa.com/womenschampionsleague/clubs/players/250161970--esse-akida/
  2. https://www.flashscore.com.ng/player/akida-esse/MsuKmWss/
  3. https://fbref.com/en/players/cffdc71b/Esse-Akida
  4. https://globalsportsarchive.com/people/soccer/esse-akida/157016/