Etí jẹ́ ẹ̀yà ara, èyí tí ènìyàn àti ẹranko fi ń gbọ́ ọ̀rọ̀. Ènìyàn àti ẹran ọ̀sìn, (tí òyìnbó ń pè ní "mammals") ní etí méjì. A lè pín etí sí ẹ̀yà mẹ́ta; etí ìta, etí àárín àti etí inú, awon ẹ̀yà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ń ṣiṣẹ́ papọ̀ láti mú kí ènìyàn tàbí ẹranko gbọ́rọ̀. Ìjàm̀bá sí etí (pàápàá jù lo; ìlù etí) le fa àìgbọ́ràn tàbí ìṣòro pẹ̀lú ọ̀rọ̀ gbígbọ́.

Etí
Human (external) ear
Eti Eniyan

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe