Etenesh Diro Neda ni a bini ọjọ kẹwa, óṣu May, Ọdun 1991 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede Ethiopia[1][2].[3]

Etenesh Diro
Etenesh Diro, 2019
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí10 Oṣù Kàrún 1991 (1991-05-10) (ọmọ ọdún 33)
Height1.68 m (5 ft 6 in)
Weight49kg
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáTrack and field
Event(s)3000 metres steeplechase

Aṣèyọri

àtúnṣe

Etenesh kopa ninu olympics ti 2012 ati 2016 lori mita ti ẹgbẹrun mẹta ti steeplechase[4]. Ni ọdun 2012, Diro kopa ninu àṣekagba ere Olympic to waye ni London pẹlu ipo kẹfa pẹlu wakati 9:19.89[5]. Ni ọdun 2013, Diro kopa ninu idije agbaye ti mita ẹgbẹrun mẹta to si pari pẹlu ipo kaarun pẹlu wakati 9:16.97. Ni ọdun 2017, Etenesh kopa ninu idije agbaye ti London ti mita ẹgbẹrun mẹta to si pari pẹlu ipo keje pẹlu wakati 9:22.46.

Àwọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Diro Details
  2. Etenesh Diro Profile
  3. "Etenesh DIRO Biography, Olympic Medals, Records and Age". Olympics.com. 2018-06-27. Retrieved 2023-04-15. 
  4. Steeplechase 3000m
  5. Olympics