Etikun ti Barbary (A tun mọ si Barbary, Berbery tabi Etikun ti Berber) jẹ orukọ ta fun agbegbe etikun ti ariwa ilẹ Afrika tabi Mahhreb papa julọ Ibudo Ottoman pẹlu rẹ ni adele to wa ni Algiers, Tripoli, Beylik ti Tunis ati Sultanata ti Morroco lati century ti mẹrin dinlogun de ọkam dinlogun. Órukọ yii ni a fayọ lati exonym ti awọn Berber.

A 17th-century map by the Dutch cartographer Jan Janssonius

Itan Etikun ti Barbary àtúnṣe

Itọkasi àtúnṣe