Ewé jẹ́ àkójọ pọ̀ orúkọ fún àwọn ẹtúntún igi oríṣríṣi tí a lè fojú rí.

The diversity of leaves
Leaf of Tilia tomentosa (Silver lime tree)
Diagram of a simple leaf.
Top and Right: Staghorn Sumac, Rhus typhina (Compound Leaf)
Bottom: Skunk Cabbage, Symplocarpus foetidus (Simple Leaf)
1. Apex
2. Primary Vein
3. Secondary Vein
4. Lamina
5. Leaf Margin
6. Petiole

Ìrísí rẹ̀ àtúnṣe

Ewé jẹ́ ohun tí ó ma ń sába rí pẹlẹbẹ, ó ma ń ní ilà tẹ́ẹ́rẹ́ láàrin bí ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí ni ewé rẹ̀ ṣe ma ń falà sára. Ewé sábà m ń hù sí ara tabí orí igi lọ́pọ̀ ìgbà, èyí náà tún dá lé irúfẹ́ ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan. Híhù igi sára ewé ma ń bẹ̀rẹ̀ láti àárin méjì. Apapọ̀ àárin igi ati ewé orí igi ni ó di ẹ̀ka igi. Ewé ma ń dàgba sókè látàrí omi ati ìtanṣán Oòrùn (photosynthesis) tí ó bá tan si ni ó fi ń gbéra sókè. [1][2][3][4] lọ́pọ̀ Ìgbà, gbogbo ewé kọ́ ló ma ń rí bákan náà, ọ̀pọ̀ ma ń dán lára,ọ̀pọ̀ sì ma ń hurun,ọ̀pọ̀ ma ń ní ẹ[[ẹ̀gún lára, nígbà tí ọ̀pọ̀ ma hani lọ́wọ́ [1]. [5] Ohun tí ó ma ń ṣokùn fà àwọ̀ olómi aró gírínì tí ewé ma ń ní ohun tí wọ́n pè ní kílórófì (chlorophyll). Èròjà yí ṣe.pàtàkì fún ìrú gọ́gọ́ ati ìdàgbàsókè ewé àti igi lápapọ̀, nítorí òun ni ó yíra padà sí óúnjẹ fún ewé ẹ́yìn tí ó bá ti gba ìtansán òrùn sára tán.

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe