Eze Ukwu
Eze Ukwu (1799–1862) jẹ Obi Kẹ̀dogún tí ìlú Otolo ati Igwe ti ijoba Nnewi . Òun ni olórí ati aṣaaju-ẹmi ni Nnewi, tó jẹ ìlú Igbo ni Naijiria. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Nnofo Royal idile ati arọ́pò bàbá rẹ̀ Eze Chukwu . Láìdàbí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọba ilẹ̀ Igbo, àwọn ọba tí wà ní Nnewi kí àwọn ará òyìnbó tó dé.