Fàsáásí Ọlábánkẹwin (Dágunró)
Fàsáásí Ọlábánkẹwin tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dágunró jẹ́ òṣèré orí ìtàgé oun sinimá àgbéléwò,ọmọ bíbí ìlú Òṣogbo ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]
Àwọn sinimá tí ó ti ṣe
àtúnṣe- Màlúù funfun
- Kàkà kí'lẹ̀ kú(2008)
- Inúnibíni (2007)
Ìkìlọ̀ agba (2008) àti bẹ́ẹ̀ beẹ̀ lọ.[2]
Ikú rẹ̀
àtúnṣeFàsáásí si olóògbé ni ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹfà ọdún 2019. Sílú Eko.
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "BREAKING: Yoruba movie actor, Fasasi 'Dagunro' Olabanke, is dead". Within Nigeria. 2019-06-13. Retrieved 2020-01-20.
- ↑ "Veteran Yoruba movie actor, Fasasi Olabankewin, is dead". Premium Times Nigeria. 2019-06-13. Retrieved 2020-01-20.