Fèrèsé jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà Ilé tí ó ma ń wà ní àárín ògiri méjì ilé. Ósì tún lè jẹ́ gíláàsì tí a fi sí ara ọkọ̀ láti lè jẹ́ kí òye, ohùn, tàbí afẹ́rẹ́ ó wọlé.

Ìyátọ́ fèrèsé ayé òde òní àti ayé àtijọ́

àtúnṣe

Láyé àtijọ́, ọ̀pọ̀ àwọn fèrèsé ló ma ń jẹ́ Pákó tí a figi ṣe, pàá pàá jùlọ ilé tí àwọn aláìní ma ń gbé ni wọ́n ma ń fi páànù àlòkù ṣe fèrèsé tàbí lẹ̀kùn. Ṣùgbọ́n láyé òde òní, àwọn gíláàsì tí ó ń dán gbinrin ni wón ma ń lò láti fi ṣe fèrèsé. [1]

Ìwúlò Fèrèsé

àtúnṣe

Fèrèsé wù lò láti jẹ́ kí afẹ́fẹ́ ó wọlé yálà nígbà oru, ó sì yan ma ń jẹ́ kí a sa fún òtútù lásìkò òjò, ọyẹ́, àti ọgìnìntì

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Window". The Free Dictionary By Farlex. Retrieved May 19, 2012.