Félix Houphouët-Boigny
Félix Houphouët-Boigny (ìpè Faransé: [feˈliks uˈfwɛt bwaˈɲi][1]) (18 October 1905 – 7 December 1993), ti awon ololufe re n pe ni Papa Houphouët tabi Le Vieux, je Aare akoko orile-ede Côte d'Ivoire lati 1960 de 1993.
Félix Houphouët-Boigny | |
---|---|
1st President of Côte d'Ivoire | |
In office 3 November 1960 – 7 December 1993 | |
Asíwájú | None (position first established) |
Arọ́pò | Henri Konan Bédié |
Prime Minister of Côte d'Ivoire | |
In office 7 August 1960 – 27 November 1960 | |
Asíwájú | None (position first established) |
Arọ́pò | None (position abolished) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Yamoussoukro, Côte d'Ivoire | 18 Oṣù Kẹ̀wá 1905
Aláìsí | 7 December 1993 Côte d'Ivoire | (ọmọ ọdún 88)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ivorian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party of Côte d'Ivoire |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Marie-Thérèse Houphouët-Boigny |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Noble, Kenneth B. (1994-02-08). "For Ivory Coast's Founder, Lavish Funeral". New York Times. http://query.nytimes.com/gst/fullpage.html?res=9E07E1D61638F93BA35751C0A962958260&sec=&spon=&pagewanted=all. Retrieved 2008-07-22.