Félix Antoine Tshisekedi Tshilombo[1] (Faransé: [feliks ɑ̃twan tʃizək(ə)di tʃilɔ̃bo]; ọjọ́ìbí 13 June 1963)[2] ni olóṣèlú ará Kóngò tó ti jẹ́ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò láti 25 January 2019.[3]


Félix Tshisekedi
Félix Tshisekedi in 2019
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò 5k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
25 January 2019
Alákóso ÀgbàBruno Tshibala
Sylvestre Ilunga
AsíwájúJoseph Kabila
Leader of the Union for Democracy and Social Progress
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
31 March 2018
AsíwájúÉtienne Tshisekedi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹfà 1963 (1963-06-13) (ọmọ ọdún 61)
Léopoldville, Congo-Léopoldville (now Kinshasa, Democratic Republic of the Congo)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnion for Democracy and Social Progress
(Àwọn) olólùfẹ́Denise Nyakéru Tshisekedi
Àwọn òbíÉtienne Tshisekedi
Marthe Kasalu Jibikila
Websitehttps://presidence.cd


Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Félix Tshisekedi investi candidat du parti historique d'opposition UDPS en RDC" (in French). Voice of America. 31 March 2018. Retrieved 25 May 2018. 
  2. Boisselet, Pierre (15 June 2017). "RDC : Félix Tshisekedi, au nom du père" (in French). Jeune Afrique. http://www.jeuneafrique.com/mag/444636/politique/rdc-felix-tshisekedi-nom-pere/. Retrieved 26 May 2018. 
  3. "RDC : Félix Tshisekedi s’installe dans le bureau présidentiel". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2019-05-25.