Funke Akindele

Òṣéré orí ìtàgé
(Àtúnjúwe láti Fúnkẹ́ Akíndélé)

Funke Akindele tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1977 [1]tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń Jennifer jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá [2]àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí Fúnkẹ́ sí ìlú Ìkòròdú, ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Eré orí tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "I need to know" ló mú un di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́kà òṣèrébìnrin lọ́dún 1998 sí ọdún 2002. Lọ́dún 2009, ó gba àmìn ẹ̀yẹ tí "Africa Movie Academy Award" gẹ́gẹ́ bí òṣèré tó dára jùlọ. Sinimá àgbéléwò kan tí òun fúnra rẹ̀ kọ, tí ó sìn ṣe agbátẹrù rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Jennifer" mú un gbajúmọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí àwọn ènìyàn fi fún ní orúkọ ìnagijẹ, "Jennifer" tí gbogbo ènìyàn ń pè é. Lẹ́yìn èyí, ó tún ń ṣe sinimá aláwàdà tí ó pè ní "Jennifer Diary", sinimá yìí mú un gba àmìn ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin aláwàdà tó dáńgájíá jùlọ lọ́dún 2016.[3] Fúnkẹ́ Akíndélé tí kópa nínú sinimá àgbéléwò to tì ju ọgọ́rùn-ún lọ. [4] [5] [6] [7]

Funke Akindele Bello
Funke Akindele ni ijade Africa Magic Viewers Choice Awards
Ọjọ́ìbíAkindele Olufunke Ayotunde
24 Oṣù Kẹjọ 1977 (1977-08-24) (ọmọ ọdún 47)
Ikorodu, Lagos State, Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Osere obinrin, Olupilese fiimu
Ìgbà iṣẹ́1998-present

Ààtò àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà

àtúnṣe
Ọdún Ètò Àmìn Ẹ̀yẹ Àkànṣe Iṣẹ́ Èsì
2009 Africa Movie Academy Award Best Actress Leading Role Jenifa Gbàá
2009 Nigeria Entertainment Awards Best Actress Jenifa Gbàá
2010 2010 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Leading Role (Yoruba) Oguni Aiku Wọ́n pèé
2012 2012 Nigeria Entertainment Awards Best Actress Troj Gbàá
2012 Nollywood Movies Awards Best Actress (Indigenous) Emi Abata Gbàá
2012 Best of Nollywood Awards Best Actress (English) Married but Living Single Wọ́n pèé
Zulu African Film Academy Awards Best Actress Maami and The Return of Jenifa Gbàá
2013 2013 Nollywood Movies Awards Best Actress (Leading Role) Maami Wọ́n pèé
Best Actress (Indigenous) Gbàá
2014 2014 Nigeria Entertainment Awards Best Actress (Leading Role) Agnetta O’Mpa Gbàá
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actress (Comedy) The Return of Sheri Koko Gbàá
ELOY Awards Brand Ambassador of the Year Omo Gbàá[8]
2016 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actress In Comedy Role Jenifa's Diary Gbàá
Nigeria Entertainment Awards Best Actress Series Wọ́n pèé
Naija FM Awards

Wikipedia Ètò àbò Àdéhùn ìmúlòOjú ẹ̀rọ orí tábìlì Content deleted

Naija FM Awards Sitcom Of The Year Gbàá
Best Actress in Comedy Gbàá
Africa Entertainment Legend Awards Best Actress of the Year Gbàá[9]
2016 Ghana Movies Awards Best Actress Africa Collaboration A Trip to Jamaica Gbàá [10]
2017 Africa Magic Viewers Choice Awards Best TV Series Jenifa's Diary Gbàá[11]
Best Actress in a Comedy (Movie or TV Series) Gbàá[12]
A Trip to Jamaica Wọ́n pèé
Nigeria Entertainment Awards Best Lead Actress Gbàá
2022 Africa Magic Viewers Choice Awards (AMVCA) Best Actress in a Comedy (Movie/TV Series) Omo Ghetto the Saga Gbàá [13]
2023 Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Actress In A Comedy Movie/TV Series Battle on Buka Street Yàán [14]
Best Writer Wọ́n pèé
Best Overall Movie Wọ́n pèé

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. https://m.imdb.com/name/nm2481000/bio/
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-19. Retrieved 2023-06-06. 
  3. "Watch Funke Akindele in season 4 trailer". Pulse Nigeria. 2016-01-26. Archived from the original on 2017-08-24. Retrieved 2019-12-04. 
  4. "Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today. 2015-09-30. Retrieved 2019-12-04. 
  5. NJOKU, Benjamin (2010-01-01). "I didn't snatch anybody's husband - Funke Akindele". Vanguard News. Retrieved 2019-12-04. 
  6. Kabir, Olivia (2019-01-16). "Top facts about Funke Akindele state of origin". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-12-04. 
  7. "Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online". Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online. 2019-10-21. Retrieved 2019-12-04. 
  8. "Omoni Oboli, Funke Akindele, Omawumi: All the winners from the 2014 ELOY awards - Lifestyle - Pulse" (in Èdè Jámánì). Pulse.ng. 2014-12-01. Retrieved 2016-12-17. 
  9. "Winners List - Ael Awards (Aela)". Aelaawards.com. Archived from the original on 2018-08-13. Retrieved 2016-12-17. 
  10. "Ghana Movie Awards 2016: Funke Akindele wins best actress African collaboration - Movies - Pulse" (in Èdè Jámánì). Pulse.ng. Archived from the original on 2016-12-20. Retrieved 2016-12-17. 
  11. Adeleke Afolayan (4 March 2017). "AMVCA 2017: See the full list of winners". The NET. 
  12. Chidumga Izuzu (4 March 2017). "Funke Akindele wins Best Actress in a Comedy". Pulse.Ng. Archived from the original on 10 August 2017. Retrieved 4 December 2019. 
  13. https://punchng.com/full-list-funke-akindele-ramsey-nouah-oga-sabinus-others-win-big-at-amvca/
  14. "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]