Folake Onayemi
Fọlákẹ́ Oritsegbubemi Ọ̀náyẹmí (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹwàá ọdún 1964, 14 Oṣù Kejì 2024) jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n àti olùkọ́ ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kàwé gboyè Ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ Fìlọ́sọ́fì, PhD lábala Classics. ìmọ̀ Classics lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kàwé gboyè Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ nílẹ̀ adúláwọ̀ Áfíríkà. Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú àfiwé lítíréṣọ̀ Greco-Roman àti Nàìjíríà], pàápàá jù lọ, àṣà àti ìṣe tó jẹ mọ́ obìnrin láwùjọ.
Folake Onayemi | |
---|---|
Born | October 4, 1964 |
Institutions | University of Ibadan |
Alma mater | University of Ibadan (BA) (MA) (MPhil) (PhD) |
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeFọlákẹ́ Ọ̀náyẹmí kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ Classics ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn lọ́dún 1986, bẹ́ẹ̀ náà ló tẹ̀ síwájú sí í tí ó sìn tún kàwé gboyè dìgírì kejì, followed by an MA lọ́dún 1990, MPhil lọ́dún 1997, àti PhD lọ́dún 2001; Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kàwé gboyè Ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ Fìlọ́sọ́fì, PhD lábala Classics ní Nàìjíríà, pẹ̀lú àkànṣe ìwé àṣẹ gboyè tí ó pe àkọlé rẹ́ ní Fear of Women's Beauty in Classical and African/Yoruba Literature.[1][2] Nígbà ìkàwé gboyè Ọ̀mọ̀wé (PhD), ó àsìkò náà láti ṣe òṣìṣẹ́ àlejò ní Brown University, ní Rhode Island.[1] [2]
Àṣàyàn àwọn ìwé rẹ̀
àtúnṣe- Onayemi, Folake (1998) The Medea Complex in Fagunwa's Yoruba Novel in Egbe Ifie and Dapo Adelugba (eds.) African Culture and Mythology, Ibadan: End-Time Publishing House, pp. 188 - 205.
- Onayemi, Folake (1999) The Other Woman in Classical and Yoruba Societies in Egbe Ifie (ed.) Coping with Culture, Ibadan: Opotoru Books, pp.46 - 54 .
- Onayemi, Folake (2002) Who Sacrifices - An Explanation to the Greek Question from a Yoruba Point of view, Storiae Letteratura 210, Roma. pp. 639-648.
- Onayemi, Folake (2002) Classics in Nigeria, Daedalus: University of South Africa Classical Journal. Vol. 3 No. 2.
- Onayemi, Folake (2002) Women and The Irrational in Ancient Greek and Yoruba Mythology, Ibadan Journal of Humanistic Studies Nos 11& 12 pp. 79-89.
- Onayemi, Folake (2002) Women Against Women: The Mother-in-law and Daughter- in-law Relationship in Classical and African Literature in Egbe Ifie (ed.) Papers in Honour of Tekena N. Tamuno Professor Emeritus at 70. Ibadan: Opoturu Books, pp.138 - 148.
- Onayemi, Folake (2002) Image of Women in Classical and African Proverbs and Popular Sayings, Journal of Cultural Studies Vol. 6 No. 1 pp. 114 - 133.
- Onayemi, Folake (2002) Courageous Women in Greek and Nigerian Drama, Antigone and Tegonni, Ibadan Journal of European Studies. No. 3 pp. 153 - 161.
- Onayemi, Folake (2002) Women, Sex and Power in Classical and Nigerian Drama: Lysistrata and Morountodun in Akintunde and Labeodan (eds), Women and Culture of Violence in Traditional Africa, Ibadan: Sefer Books, pp. 41 - 51.
- Onayemi, Folake (2003) Threptia and Sanjo: The Pay Back: Parent-Child Relationship in Ancient Greek and African Yoruba Cultures, Daedalus: University of South Africa Classical Journal. Vol. 4 No. 1.
- Onayemi, Folake (2004) Finding A Place: Women's Struggle for Political Authority in Ancient Roman and Nigerian Societies, Women's History Review U.K.
- Onayemi, Folake (2005) Representation of Women's Leadership in Ancient Greek and Modern Yoruba Drama: Assembly Women and Lagidigba. In Akintunde (ed.) Women Leadership: The Nigerian Context. Ibadan: Sefer Books.
- Onayemi, Folake (2006), Sin, Punishment And Forgiveness In Ancient Greek Religion: A Yoruba Assessment, Journal of Philosophy and Culture Vol. 3 (1) 2006: pp. 72-101
- Onayemi, Folake & Nigel Henry (2007), New Approaches to the Humanities: the Key Role of Classics, in Sola Akirinade (ed.), Rethinking the Humanities in Africa (Faculty of Arts, Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀), pp.241-50
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Prof. Onayemi F. | Faculty of Arts, UI". arts.ui.edu.ng. Archived from the original on 23 May 2019. Retrieved 2019-05-23.
- ↑ 2.0 2.1 "BIODATA OF PROFESSOR FOLAKE ORITSEGBUBEMI ONAYEMI" (PDF). University of Ibadan. Retrieved 2019-05-23.