Facebook jẹ́ ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lórí afẹ́fẹ́ ẹ̀rọ ayélujára. Ó jẹ́ ìkànnì tí lè ní àǹfààní sí láti orí foonu alagbeka, ẹ̀rọ kọ̀m̀puta tábìlì àti èro komputa agbelowo tí ó ní àmúmọ̀ láti já lú ayé lórí afẹ́fẹ́. Ilé Iṣẹ́ tí ó ń ṣe kòkárí rẹ̀ gúnwà sí Menlo Park, California, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ọ̀gbẹ́ni Mark Zuckerberg ní ó ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 2004. [7] [8] [9]. Alefi Facebook fòrò ránsé si olùmúlò Facebook miran, a sì tún le fi Facebook fi foto àti fidio ránsé sawon òré wa.
Type | Public |
---|---|
Area served | Worldwide |
Key people | |
Industry | |
Products | |
Revenue | ▲ US$55.838 billion |
Operating income | ▲ US$24.913 billion |
Net income | ▲ US$22.111 billion |
Total assets | ▲ US$97.334 billion |
Total equity | ▲ US$84.127 billion |
Employees | 43,030[1] |
References: [2][3][4][5][6] |
Ka eléyí náà
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ https://s21.q4cdn.com/399680738/files/doc_financials/2019/q3/FB-Q3-2019-Earnings-Release.pdf
- ↑ "Our History". Facebook. Retrieved November 7, 2018.
- ↑ Shaban, Hamza (February 20, 2019). "Digital advertising to surpass print and TV for the first time, report says". The Washington Post. Retrieved June 2, 2019.
- ↑ "FB Income Statement". NASDAQ.com.
- ↑ "FB Balance Sheet". NASDAQ.com.
- ↑ "Stats". Facebook. June 30, 2019. Retrieved July 25, 2019.
- ↑ Erickson, Christine (2012-02-03). "Facebook IPO: The Complete Guide". Mashable. Retrieved 2020-01-08.
- ↑ "Facebook - Overview, History, & Facts". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-01-08.
- ↑ Sraders, Anne (2018-10-11). "History of Facebook: Facts and What's Happening in 2018". TheStreet. Retrieved 2020-01-08.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |