Fafali Dumehasi
Fafali Dumehasi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ́ ghana ti a bini ọjọ 25, óṣu December ni ọdun 1993.Agbabọọlu naa ṣere fun Accra police gẹgẹbi goalkeeper[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 25 Oṣù Kejìlá 1993 | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Police Accra | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Wasila kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].