Fagrie Lakay (ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu karun ọdun 1997) jẹ agbabọọlu afẹsẹgba fun orilẹ-ede South Africa ti oun gba siwaju fun ẹgbẹ agbabọọlu Premier League Egypt Pyramids FC ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede South Africa.

Career statistics

àtúnṣe

Ti a bi ni Manenberg . [1]

Lakay bẹrẹ bọọlu afẹsẹgba fun Real Stars, ẹgbẹ kan ti baba rẹ jẹ. Lẹhinna o rii ipolowo kan fun awọn idanwo Santos ati pe baba rẹ mu u lọ sibẹ. [2] Lakay gba bọọlu akoko rẹ fun Santos ni National First Division ni 20 Oṣu Kẹwa Ọdun 2012 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn pẹlu FC Cape Town . O bẹrẹ ati pe o gba abala akọkọ bi Santos ṣe gba Omo Ayo ninu ìfesewonse naa 0–0. Lẹhinna o gba ominayo Akoko re wọlé ninu ifẹsẹwọnsẹ rẹ ni ọjọ kaarun OSU keji ọdun 2014 pelu Ile-ẹkọ giga Maluti FET ninu eyiti o gba wọlé ni iṣẹju 39th rẹ fun Santos ni o gbe won siwaju pelu 2–0. Sibẹsibẹ, FET College pada wa lati gba ifẹsẹwọnsẹ naa si ómí 2–2.

Ile Oke're

àtúnṣe

Lakay ti ṣere fun South Africa ni ipele ẹgbẹ awon ti o wa labẹ-17 ati labẹ-20 . Lakay gba ami ayo wọle ninu ifẹsẹwọnsẹ igbaradi fun Santos pelu agbabọọlu orilẹede naa, ti o na Dumisani Msibi ẹlẹgbẹ rẹ ti àwọn ti abẹ 20 ni goolu lati 40m, ṣaaju ifẹsẹwọnsẹ South Africa pẹlu orilẹ-ede Nigeria ni Cape Town . [2] O gba ifẹsẹwọnsẹ agbá akọkọ rẹ fun orilẹ-ede South Africa ni ọjọ ogbon Oṣu kọkanla ọdun 2014 nigbati orilẹ-ede naa gba ifẹsẹwọnsẹ pẹlu orilẹ-ede Ivory Coast . O wa bi aropo ni iṣẹju 75th fun Themba Zwane bi orilẹ-ede South Africa ti bori pelu 2–0. Nipa ṣiṣe iṣafihan akọkọ rẹ, Lakay ni ọdun 17, oṣu 5, ọjọ 30, o gba ipo naa lowo Rivaldo Coetzee o se fi itanbalẹ Gẹgẹ bi eniti o mere julo l'ojo ori lati wọ aṣọ orilẹ-ede ni ọdun 17, oṣu 11, ọjọ 25. Coetzee gba itan naa lowo balogun iko Bafana tẹlẹ Aaron Mokoena ti o jẹ Omo ọdun 18, oṣu meji, ọjọ 26 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn pẹlu egbe agbabọọlu orilẹede Botswana ni ọdun 1999. [3]

Awọn iṣiro iṣẹ

àtúnṣe

Àdàkọ:Updated[4]

Awọn miiran

àtúnṣe
Ologba Akoko Ajumọṣe Cup League Ife Abele International Lapapọ
Pipin Awọn ohun elo Awọn ibi-afẹde Awọn ohun elo Awọn ibi-afẹde Awọn ohun elo Awọn ibi-afẹde Awọn ohun elo Awọn ibi-afẹde Awọn ohun elo Awọn ibi-afẹde
Santos Ọdun 2012–13 NFD 4 0 1 0 0 0 - - 5 0
Ọdun 2013–14 NFD 14 3 0 0 2 0 - - 16 3
Ọdun 2014–15 NFD 7 0 0 0 0 0 - - 7 0
Lapapọ iṣẹ 25 3 1 0 2 0 0 0 28 3

References

àtúnṣe
  1. "Fagrie Lakay heads home to join Ajax Cape Town" (in en). Independent Online. 5 January 2018. https://www.iol.co.za/sport/soccer/psl/fagrie-lakay-heads-home-to-join-ajax-cape-town-12621365. 
  2. 2.0 2.1 Empty citation (help) 
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named auto1
  4. Àdàkọ:Soccerway

Ita ìjápọ

àtúnṣe