Faith Ikidi jẹ obinrin agbabọọlu ilẹ Naigiria ti a bini 28, óṣu febuary ni ọdun 1987 si ilu Port Hacourt. Arabinrin naa jẹ Defender fun Super Falcons ilẹ Naigiria ati Piteà IF ni Sweden[1].

Faith Michael
Faith Ikidi
Personal information
OrúkọFaith Ikidi Michael
Ọjọ́ ìbí28 Oṣù Kejì 1987 (1987-02-28) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíPort Harcourt, Nigeria
Ìga1.72 m
Playing positionDefender
Club information
Current clubPiteå IF
Number14
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2000–2001Novia Queens FC
2001–2004Bayelsa Queens FC
2004–2005Klepp IL
2004–2006QBIK
2007Eskilstuna United DFF
2009–2010Linköpings FC37(2)
2011–Piteå IF205(9)
National team
2004–Nigeria women's national football team53(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 14 October 2018.
† Appearances (Goals).

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Ni ọdun 2006, Ikidi jẹ ọkan lara awọn Elere Naigiria ti o jẹ Awọn Afirica akọkọ lati kopa ninu ere idije swedish nibi ti wọn ti jẹ aṣoju fun QBIK[2].
  • Faith ko ipa pataki ninu aṣeyọri Super Falcons ni Cup awọn Obinrin ilẹ Afirica Agbaye ni ilu Cameroun. Arabinrin naa jẹ ikan ninu awọn agba obinrin agbabọọlu ti VAVEL UK fun loruko ni ọdun 2017[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.zgr.net/en/people/faith-ikidi-biography-fact-career-awards-net-worth-and-life-story/amp
  2. http://news.bbc.co.uk/sport2/hi/football/africa/4857278.stm
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-25. Retrieved 2022-05-25.