Faizul Waheed (tí wọ́n tún mọ̀ sí Faizul Waheed Qāsmī;[1] Wọ́n bí ní ọdún 1964 , tí ó sì fi ayé lẹ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹfà, ọdún 2021) Jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀sìn Ìsìláàmù, onímọ̀ òfin ẹ̀sìn Ìsìláàmù àti onímọ̀ ìtumọ̀ Kòrání Jammu àti Kashmir, tí ó jẹ́ olórí àwọn Múfútí fún Markaz-ul-Ma'arif, ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ fún ẹ̀sìn Ìsìláàmù ní Bathindi, Jammu. Ó kọ Haiz al-Mannān, Kòránì àkọ́kọ́ tó tú sí àti ní àlàyé ní Èdè Gojri

Mufti
Faizul Waheed
Faizul Waheed in 2021
Ọjọ́ìbíÀdàkọ:Birth year
Dodhasan Bala, Thanamandi, Rajouri
Aláìsí (ọmọ ọdún 56)
ASCOMS, Jammu
Iléẹ̀kọ́ gíga
Notable workFaiz al-Mannān

Àwọn Ìwé Rẹ̀

àtúnṣe

Faizul Waheed kọ "Faiz al-Mannān",[2] ìtumọ̀ Al-Qur’an àkọ́kọ́ láíláí ní èdè Gojri.[3]

Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ mìíràn pẹ̀lú:[4]

  • Sirājum Muneera ("Àtùpà dídán, ìtàn ìgbésí ayé wòlíì Islam Muhammad.")
  • Pāki ke Masā'il Qur'ān-o-Hadees ki Roshni Mein (The Rules of Purity in the Light of Qur'ān and Hadith)
  • Mareez-o-Mayyit awr Warāsat ke Ahkām Qur'ān-o-Hadees ki Roshni Mein ("Àwọn òfin ti Alárẹ̀, Olókùú àti Ìjogúnbá nínú Ìmọ́lẹ̀ Al-Qur'ān àti Hadith")

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "عملی زندگی میں جذبات کے بجائے حکمت عملی اور منصوبہ بندی سے آپ کو کام کرنا ہوگا". Millat Times. 28 April 2019. Archived from the original on 2 June 2021. https://web.archive.org/web/20210602215426/https://urdu.millattimes.com/story/40189. 
  2. Àdàkọ:Cite thesis
  3. "J&K mufti who translated Quran into Gojri, helped tribal children pursue education, dies" (in en). The Indian Express. 2021-06-02. https://indianexpress.com/article/india/jk-mufti-who-translated-quran-into-gojri-helped-tribal-children-pursue-education-dies-7340284/. 
  4. Web, GK. "Mufti Faiz-ul-Waheed, who first translated Qur'an into Gojri language passes away" (in en). Greater Kashmir. https://www.greaterkashmir.com/jammu/mufti-faiz-ul-waheed-who-first-translated-quran-into-gojri-language-passes-away.