Fathia Absie
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Fathia Absie jẹ́ òṣèrébìnrin, ònkọ̀tàn, olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Sòmálíà àti Amẹ́ríkà. Ó ti ṣiṣẹ́ lóri ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí àti àwọn eré àròṣe, ó sì ti kọ ìwé-ìtàn kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Imperceptible Peace Maker.
Fathia Absie فتحية إبسيآ | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mogadishu, Somalia |
Orílẹ̀-èdè | Somali, American |
Iṣẹ́ | Writer, producer, actress and filmmaker |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣe- Broken Dreams (2011)
- The Lobby (2015)
- A Stray (2016)