Fati Mohammed tí a bí ní ọjọ́ kẹrin osù kẹfà ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ará ilẹ̀ Ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bí asọ́lé. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kópa ní bi 2003 FIFA Women's World Cup àti 2007 FIFA World Cup Women. Lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Robert Morris College ní Amẹrika. [1]

Fati Mohammed
Personal information
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kẹrin osù kẹfà ọdún 1979
Playing positionAsọ́lé
National team
Ghana13(0)
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help)